Le Symbole de Nicée en langue yoruba Iwé ti Nicé
Le Symbole de Nicée en langue yoruba Iwé ti Nicé
Mo gba gbor niou olohun kan chocho, baba wa unla, ti oda ayé ati orun, ati unti ari ati yé a iri.
Ninou Jesu Christi kan , omor olorhun kan chocho, ti olohun bi shaju gbogbo éniyan; olorhun awon olorhun; ti oba olorhun chichè lati da ilé ayé ta wa Eniti toriwa awa ormon éniyan; owa ilé ayé lati gba awon èchè wa, ti Maria bi guèguè bi ormon éniyan; on kan léri agbélébou,ojouya labè Pilatou, on kpa; ojorkèta oji undé otoun gba gbara kun ghèguè bi awon iwé sor, ogoké lor olor joko lapka otun Edumaré, ibiti okoro la ti dajor omor éniyan.
Mo gba ninou iwé mimon, èniti to da wa, baba ti fid é léri awon ormoun, ti awoon èsor.
Mo gba gbor ninou chuchi catoliki ati apostolic. Mo gba ninou ojor ibi yé kan , ninou idari èshè, mo douro é ojor idjidé awon okou; ati agéssa yé lor. Ami.